
SHON PE (Count Your Money)
From A Street Kid's Diary (Disk 2) · Released 2 October 2026 · Dapper Music & Entertainment · EExplicit

From A Street Kid's Diary (Disk 2) · Released 2 October 2026 · Dapper Music & Entertainment · EExplicit
Humzey (Humzey)
One pesin no fit carry Forest
Eeyan kan o le dagbo gbe, hm
Emi ni mo gbera mi de'bẹ
Made my decision, mo sa kuro n'le, oh
Dem wan' make my matter get K-leg
Ọmọ aye o le sa fun aye
'Cause aye ole o
Aye gbọpọlọ ni, nigga, ṣo n ye o?
Aye n sare lọ ni, bọbọ, ṣo n le o?
Count your money, money, baby, ṣo n pe o?
Ṣo n pe o? (Ṣo n pe?) Ṣo n pe o?
(Uhn-uhn-uhn, Ṣo n pe?)
Ṣo n pe o? (Ṣo n pe?) Ṣo n pe o?
(Oh-uhn-uhn, Ṣo n pe?)
Ṣo n pe o? (Ṣo n pe?) Ṣo n pe o?
(Uhn-uhn-uhn, Ṣo n pe?)
Ṣo n pe o? (Ṣo n pe?) Ṣo n pe o?
(Oh-uhn-uhn, Ṣo n pe?)
Count your money, money, money
(Ka'wo ẹ, ka'wo ẹ, ka'wo ẹ, ka'wo ẹ)
Count your money, money, money
(Ka'wo ẹ, ka'wo ẹ, ka'wo ẹ, ka'wo ẹ)
Count your money, money, money
(Ka'wo ẹ, ka'wo ẹ, ka'wo ẹ, ka'wo ẹ)
Count your money, money, money
Count your money, money, money
I go find greener pasture
Mo sare lọ ba pastor
I don tire, tire for the hustle, hustle every day
Rain it's storming, when it's raining na me dey for me o (o-o)
Meji, meji (ye-ye-ye)
Mẹta, mẹta (ye-ye-ye)
Maa lọ ita (ye-ye-ye)
Outside o da (ye-ye-ye)
All the boys dem kala (ye-ye-ye)
All the girls no normal (ye-ye-ye)
Ṣa tẹlẹ jẹjẹ, jẹjẹ, jẹjẹ, jẹjẹ, jẹjẹ
Aye ole o
Aye gbọpọlọ ni, nigga, ṣo n ye o?
Aye n sare lọ ni, bọbọ, ṣo n le o?
Count your money, money, baby, ṣo n pe o?
Ṣo n pe o? (Ṣo n pe?) Ṣo n pe o?
(Uhn-uhn-uhn, Ṣo n pe?)
Ṣo n pe o? (Ṣo n pe?) Ṣo n pe o?
(Oh-uhn-uhn, Ṣo n pe?)
Ṣo n pe o? (Ṣo n pe?) Ṣo n pe o?
(Uhn-uhn-uhn, Ṣo n pe?)
Ṣo n pe o? (Ṣo n pe?) Ṣo n pe o?
(Oh-uhn-uhn, Ṣo n pe?)
Count your money, money, money
(Ka'wo ẹ, ka'wo ẹ, ka'wo ẹ, ka'wo ẹ)
Count your money, money, money
(Ka'wo ẹ, ka'wo ẹ, ka'wo ẹ, ka'wo ẹ)
Count your money, money, money
(Ka'wo ẹ, ka'wo ẹ, ka'wo ẹ, ka'wo ẹ)
Count your money, money, money
Lyrics from LRCLIB
Own this song? Email takedown@jamtap.app to have it removed.