9 cover

miss u ii (nriri)

From 9 · Released 8 October 2026 · Dangbana Republik Records / EMPIRE

2:30
Details from Deezer

Lyrics

Boss

Ah-ah, ah, no, no

Ah-ah, ah, no, no

I miss you bad, my bae

When you comot, e dey give me migraine

Tell me, "Don't do that", o máa ṣe

Like jollof, I go need your plate

Agidi wọn ńbẹ̀, ọ̀gbẹ́ni, keep your company

Your decision, ó ti jẹ́ kí n kọ́gbọ́n

Mi ò ní dandan ni kó fẹ́ mi, uh-uh, you get it

Kò ṣáà ti máa kẹ́ mi, ọmọ, uh

Ah-ah, nriri, nriri, nriri is your love

Nriri, nriri, nriri your love

Ọnọme, ó kéré nínú ayé, between me and you, ó sọ mí di bolo

Ìyẹn ò ní kí èmi má lọ́lé

On my rhythm and blues, ọrẹ́ntẹ́ mi pọ̀ gan

I miss you bad, my bae

When you comot, e dey give me migraine

Tell me, "Don't do that", o máa ṣe

Like jollof, I go need your plate

Agidi wọn ńbẹ̀, ọ̀gbẹ́ni, keep your company

Your decision, ó ti jẹ́ kí n kọ́gbọ́n

Mi ò ní dandan ni kó (Fẹ́ mi), uh-uh, you get it (Get it)

Kò ṣáà ti máa kẹ́ mi, ọmọ, uh

Along the line

Ọmọ, ìfẹ́ ma whine, abobi ṣa

Baby, even if you don't let me, I'll hold you down

Gbàgbọ́, ṣé jẹ́ ni, we run the town (Yeah, yeah)

Tell me things that I don't know

When I'm doing it, má sọ f'ọ́tọ̀

T'orí ìwọ nì wa, mọ́ ti r'àpò lọ

Make me your idolo (Yeah, yeah)

Ah-ah, nriri, nriri, nriri is your love

Nriri, nriri, nriri your love

Ọnọme, ó kéré nínú ayé, between me and you, ó sọ mí di bolo

Ìyẹn ò ní kí èmi má lọ́lé

On my rhythm and blues, ọrẹ́ntẹ́ mi pọ̀ gan

I miss you bad, my bae

When you comot, e dey give me migraine

Tell me, "Don't do that", o máa ṣe

Like jollof, I go need your plate

Agidi wọn ńbẹ̀, ọ̀gbẹ́ni (Ọ̀gbẹ́ni), keep your company ('Pany)

Your decision, ó ti jẹ́ kí n kọ́gbọ́n

Mi ò ní dandan ni kó (Fẹ́ mi), uh-uh, you get it (Get it)

Kò ṣáà ti máa kẹ́ mi, ọmọ, uh

Lyrics from LRCLIB

Own this song? Email takedown@jamtap.app to have it removed.